Lagosians.com

Nigerian social network connecting Lagosians and Lovers of Lagos worldwide

Saheed Osupa (Ifokanbale 1)

Information

Saheed Osupa (Ifokanbale 1)

Members: 14
Latest Activity: Apr 4, 2011

Discussion Forum

The Man called OSUPA 1 Reply

Started by Moshood. Last reply by Moshood May 20, 2009.

Comment Wall

Add a Comment

You need to be a member of Saheed Osupa (Ifokanbale 1) to add comments!

Comment by yusuf olanrewaju on October 4, 2010 at 12:28
one love to all olufimo member
Comment by olanrewaju aromokun on January 25, 2010 at 22:34
kokoro alate toun tate ni, ohu alate toun tate ni, abounde lorun sa laiye onikaluku loti ni tie lara. Egbo na talo mo na, ta lomo na, ki lo'birin nfe, obirin nfe ite lorun, okunrin o de le fun, ati wa jo gbe po, ba wo lade le se, kose mani sa fun obirin pelu okunrin. Etun gbo na talo mo na, talo mo na, ki lo'kunrin o fe, okunrin o fe afoju di, iwa obirin de ni yen, ati wa jo gbe po, ba wo lade le se, kose mani sa okunrin pelu obirin. Eri bi obirin ba ko oko sile o, ani mo gba isin mi, mo gba ominira gbogbo ma'su ma'to o, mo gbo minira gbogbo ni bo longba nlo, bio si t'omo nibe ki ni mofe fi okunrin se gan. Bi Okunrin ba ka'aya sile o, a ni mo ko isoro, mo ko isoro to fe fun mi l'oron pa, mo ko isoro to fe ga ju emi mi lo,bio si t'omo nibe ki ni mofe fi obirin se gan. iyawo mi ni sugbon moferan sugbon e mo, emi gan ni o fe femi fe sugbon mi, bo fe emi ni kan, ni bo ni o'fi sugbon mi si, bo fe elomiran o le tun ju temi gan lo. oje l'obinrin je f'alagbede, afi okunrin t'oba gbon,
Comment by EMKAYBEE on January 25, 2010 at 10:00
GBOGBO IBI TI MO BA NLO MO NLO PELU OLORUN, ODE APERIN GAN NLO PELU EGBE, ODE APEFON GAN NLO PELU AJAMU, ODE OGOGO GAN NLO TOUN TOMI, OMI LABUWE OMI DE LABUMU, OMI OSE BADITE, OMI O SE BABINU, DEDE GBOGBO ENI BABI NU GBOGBO WON TI FIDIREMI, KORO ANA TO DARI LODO LOMUMI
Comment by Moshood on December 5, 2009 at 21:41
Gbogbo nteda nse L'aiye (2), kirakita ma too tan, igbeyin eda maa too de. Eda nbo wa be Adamo, Adamo abe Noah, Noah abe Ibrahimo, Ibrahimo abe Musaaaa, Musa abe Isaa, Isaa nbo wa be Muhammad mi Rosulullah, awa be Olohun mi fun eda bo ba lalaira. Allahumo Solli Alla Seyidina Wayarobbi Seyidina Muhammad
Comment by EMKAYBEE on November 23, 2009 at 8:25
Won wa ni naka ki won to ma fi awa ahon ma, tori pe OLOUN YOO MA BUNKU WA 4EVA
Comment by EMKAYBEE on November 16, 2009 at 10:09
Latibi lo na ni ,oju to pawo ko mai ti wo poster, won wa ni naka kon to ma fi awo ahon ma, ti awa ba ti yo, gbogbo aye ni amo pe ati de, tori ibi giga ni tawa
Comment by olanrewaju aromokun on November 14, 2009 at 0:27
i remember when i was nobody, when the going was rough & tough, i never thought i 'd be somebody. i was crying i had no shoes, until i saw someone without leg.
Comment by olanrewaju aromokun on November 14, 2009 at 0:05
olorun lonse ohun gbogbo, eda kan le ma tiraka, ibi teni kan se de o, to lo ti su hun, pe mo jawo pe ni bukata temi, ni nana loke ba pa ri ise.
Comment by olanrewaju aromokun on November 13, 2009 at 22:40
olorun oba nikan lato gboju le, ato gboju le ato farati bi oke. inu eda le, enia loni dudu, ogu su aro kan ko dudu to inu eda, ko ma seni ti onika ninu, oloju eni le se ni. mama so pe enyan won, sugbon bon se nma nso, moro pe iro ni won npa, mo wa lo si oja oyingbo, mo ri tero po repete, mo tun d'oshodi oke, mo wole won nshon bi omi. mo wa lo ba mama mi, enyan won teun so, ko ma ye mi tofa, ............ mama lero to ri yen to lo bi ile bi eni, won leyan buruku lo po bi igbe laiye, eni rere won joju lo ko wo po, ori si leyan bi orisi risi aso. iwo ore mi gbiyanju se prayer s'olorun, eleti gbaroye loba Allahu sati.
Comment by olanrewaju aromokun on November 13, 2009 at 22:12
Matagbamole 1, e tie gbona, kini kini kilode, se bi kaluku lonse tie, gbogbo igba t'erin logbo lowo, se bi olo laju o binu, igba ti kiniun wa nse tie, e wa le fe pololaju lejo, iro ni kolejo nu.
 

Members (14)

 
 
 

© 2012   Created by eLagos.

Badges  |  Report an Issue  |  Terms of Service